Inaki ti sagbako lowo olode: E wa wo igbeyin ijimere
Olode kan ni ipinle Delta ni a gbo wi pe owo re ba inaki yii eleyii to mu bale pelu bajinatu. Bi aworan yii se yoju sori ayelujara ni opo awon eniyan ti n ba inaki naa kaanu. Won ni o ye ki awon eniyan dudu ti dekun iru iwa bayii.
0 comments:
Post a Comment