Gege bi a ti gbo, awon agbebon yii yinbo kikankikan bi won se wole, bakan naa ni won un beere fun awon oko to wa ninu ogba naa.
Sugnon ohun to joju ni wi pe, won fi leta kan sile lo. Ninu leta naa ni won ti n se kilokilo si okan pataki osise EFCC kan ti oruko re n je, Ishaku Sharu.
Ogbeni Ishaku Sharu yii lagbo wi pe o maa n sise olotelemuye fun ajo naa lati ridi awon ojelu oloselu Naijiria ti won ko owo ilu je. Ninu leta naa, won ni ti okunrin naa ko ba jawe agbeje, awon yoo seku padanu ni.
0 comments:
Post a Comment