Omokunrin to ti ni iyawo ati omo meji salaye wi pe, ise yii naa ni oun fi toju ebi oun. Koda, o tun sakaye wi pe, iyawo oun naa ti naa ti n kiri iresi ofada.
Awon eniyan ma n fimi rerin ti mo ba ti n kiri iresi- Niyi oniresi ofada
Okunrin kan to pe oruko ara re ni Adeniyi Hammed ni agbegbe Yaba ti salaye wi pe, awon eniyan won ma fi oun rerin ti ohun ba n kiri iresi ofada. O ni aisi agbara ni ko je ki oun pari ileewe, eleyii yii lo si mu oun ya sidi iresi ofada.
0 comments:
Post a Comment