Lara oro ti n fo kiri ori ayelujara bayii ni eyi ti n so wi pe, Funke Akindele ti finu soyun. Oro yii lo bere nibi ti awon kan ti kofiri Jenifa eleyii ti inu re ta sita bi eni to loyun.
Bi o tile je wi pe Suliya ko ti fenuso boya iro tabi otito ni oro naa, sugbon gbogbo eniyan ni won ti bere si ni ki ku orii re ayo to deba a.
Oro to wa nile yii dabi eni a gbe iyawo bo wa ba, won ni ki i gbe ori igana woran.
0 comments:
Post a Comment