Kete ti won gbo irora obirin naa ni won sare yanda oko won lati gbe de ile iwosan nibi won ti gbe n gbebi fun un lowolowo bayii.
Awon olopaa Ambode ti gbemi alaboyun la ni Ketu
Gbogbo ara ilu lo ti n gbe oriyin nla fun awon olopaa RRS ti ipinle Eko pelu bi won se seranwo fun alaboyun ti omo n mu ni oju titi ni agbegbe Ketu.
0 comments:
Post a Comment