Bayii ni e se le lo alubọsa aayu (garlic) fun Òtútù Igbaaya (Pneumonia) |
Eyi ni alaye
fun iwosan eniyan to ni otutu igbaaya ti a mọ si Pneumonia.
Èròjà: Alubọsa aayu (garlic)
Ìpèsè: A ma wa
alubosa aayu (garlic), ẹ lọ lati fun omi rẹ jade.
Lílò:A ma mu sibi kan (a spoon) omi ti fun jade lara alubosa aayu (garlic). Bakan naa, a ma fi
omi naa pa igbaaya ati eyin (chest and back).
0 comments:
Post a Comment