Biafra: Ago olopaa ti awon IPOB danasun ni Aba ni yii
Ago olopaa,Ariara Police Station, to kale siluu Aba ti awon omo IPOB ti won pe fun Biafra baje ni yii. Ohun ti a gbo ni wi pe won danu su tesan naa ti gbogbo re se jona wuruwuru.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
9/15/2017 12:23:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment