Babatunde Omidina aka Baba Suwe |
Bi o ba je wi pe bi a se sowopo se oku olokunrun ni won se n toju re. Boya olokunrun ko ba si wa laye. Leyin bi osu meta ti Yomi Fabiyi ti ke gbajari fun iranlowo Babatunde Omidana ti gbogbo eniyan mo si Baba Suwe, sibesibe, ipo ailera re ko ti bo sipo.
Actor Yomi Fabiyi has raised the alarm over the health of veteran Yoruba actor, Baba Suwe, urging Nigerians to remember him in their prayers.
He said the veteran actor is still traumatised over the the Nigerian Drug Law Enforcement Agency (NDLEA) incident where he was detained after he was accused of injecting drugs.
Fabiyi said the long pipe inserted through his anus seemed to be having effects on Baba Suwe as he can no longer move to movie locations.
A statement he circulated yesterday reads: “I am calling on all senior colleagues in the entertainment world especially those close to Baba Suwe because I don’t have everyone’s contact to please reach out to him as soon as possible." Iroyin jade ninu iwe iroyin Daily Post
Yomi Fabiyi |
Awon kan tile se alaye wi pe, Baba Suwe ko le dide rin mo bi ti tele. Kosi si idaniloju wi pe okunrin naa le pada senu ise tiata mo pelu bi ipo ailera se n buru si i lojoojumo.
0 comments:
Post a Comment