
Gomina Abiola Ajimobi ati aya re, Florence Ajimobi gbalejo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, Christopher Alao-Akala niluu London. Lai se alaye rẹpẹtẹ, o daju wi pe igbaladun ni won wa.
Sugbon sa, se ki i se wi pe won tun pete tuntun nipa oro oselu?
0 comments:
Post a Comment