Aimoye emi lo sofo, dukia parun, opolopo awon omode ni won gbe igbe aye airi ounje je ati aisan.
[Foto] Ohun to sele nigba ogun Biafra aye Ojukwu
Sebi won ni ti omode ko batan, yoo ba aroba. Aroba si ni baba itan. Die lara awon aworan ogun Biafra to waye ni yii nigba aye Ojukwu.
0 comments:
Post a Comment