O ti pe ti awon eniyan ti maa n soro alufansa si i wi pe, o ni lati je omo oninabi ni pelu awon foto to ma n fi ihoho ara re han- paapa julo, igbaaya re.
N se ni omobirin naa ba kuku so fun won wi pe, ki won ye gbe aheso mo, ati wi pe otito ni gbogbo ohun ti won so kiri.
Eni ori ba si n fo le lo si tesan lati lo pe olopaa wa.
0 comments:
Post a Comment