Smiley face

"Pasuma @ 50 to n se bi omo 15" - Talo sọ bẹẹ? Wàhálà Paso àti Malaika sì ń gbóná

Bí ó tilè jé wí pé Sulaimon Alao Malaika kò ju ọmọ ọdún merinlelogoji (44)lọ, ó fi àgbà hàn Pasuma tó jẹ́ ọmọ  àádọ́ta ọdún (50), nipa ìwà ologbon to fihan." - Bolarinwa Hammed lọ soro yii lori Facebook.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ní won retí Malaika láti ju akasu oro ranse padà sí Pasuma nígbà tí Pasuma pe e ní omo lẹ́yìn, eléyìí to ni ko to ẹni tí wọ́n lè pè ní akegbe tàbí ọ̀rẹ́ òun láéláé.

Aìfèsìpadà padà Malaika jẹ́ ohun iwuri fún àwon olólùfẹ́ rẹ káàkiri àgbáyé. Awon kan tun se àpèjúwe Pasuma gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọdún 50 tí ń ṣe bí 15 lórí ayelujara.

Ṣùgbọ́n kí ló fà wúlẹ̀wúlẹ̀ ọ̀rọ̀ yii?

Ẹbí arabambi fọ nikete ti ìkùnsínú díè kan waye láàárín Pasuma ati K1. Ni àkókò yìí ni Iba Wasila kede wi pe oun kìí se Otunba ẹnikẹ́ni mọ. A ti wi pe oun gan-an tí di Oganla.

Alaye sì ń tèsíwájú...

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment