Smiley face

Davido pahùn dà, "Mr. Dele na my Daddy" : Ìjà parí láàárín ìdílé Adeleke ati Momodu

Ìkùnsínú to bẹ sile ni awon akoko kan seyin láàárín ìdílé Adedeji Adeleke ati ìdílé Dele Momodu lọ ti pari bayii.

Wàhálà  yìí ló bere nígbà tí ìdílé Adeleke fe gbe ọmọ tí Sophia Momodu bi fun Davido sa lọ lai naani ìyá ọmọ náà.

Bí ó tilè jé wí pé ìdílé Davido lowo, sugbon gbogbo agbára iroyin ti alase Ovation ni lo fi dé won lona láti rí ọmọ náà gbé kọjá ẹnu bodé.

Ṣùgbọ́n báyìí, ija naa ti pari. Kódà, Davido wá korin nibi ayeye chrismas carol eléyìí tí Dele Momodu gbé kale.

Níwájú Wòlíì àgbáyé láti ìlú London, Esther Ajayi, ní Davido tí tẹrí ba fún oga Momodu tí àwọn méjèèjì sì di mo ara wọn gẹ́gẹ́ bí bàbá sì ọmọ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment