Lana ode yii ni Bukola Arugba ń ṣe ọjọ́ ìbí eléyìí tí ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn ń bá yọ káàkiri origun merin àgbáyé. Awon tokotaya náà tí padà wá dúpẹ́ pelu ife tí àwọn ènìyàn fi hàn sí tọkọtaya náà.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment