Tayo Odueke tí gbogbo ènìyàn mo sì Sikiratu Sindodo ni omobirin rẹ, Naomi Suleman, tí pé ẹni ogún ọdún bayii.
Bí ó tilè jé wí pé ẹnikẹ́ni kò mọ Baba omo yìí, bákan náà ni oserebirin yii ko si ni ile ọkùnrin kankan.
Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìwádìí, Sikiratu tí fi igba kan fe Sule Alao Malaika. Eleyii ti awon mejeeji jọ gbádùn ara wọn dáadáa kí wón tó pínyà.
0 comments:
Post a Comment