Smiley face

Rògbòdìyàn láàárín Pasuma ati Malaika: Paso tí lọ bẹ Malaika

Wasiu Alabi Pasuma tí tọrọ àforíjìn lọ́wọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ nípa bó ṣe pé Sule Alao Malaika ni ọmọlẹ́yìn rẹ - "my boy. "

Lọ́jọ́ tí Malaika n sì ilé rẹ tuntun, aimoye awon olorin ni won debe ṣùgbọ́n Paso o yoju.

Oniroyin kan tó bá Pasuma pade lojo naa béèrè ìdí tí kò fi wá nibi isile ọrẹ rẹ. Kàkà ki Pasuma dáhùn, ó ní ọmọlẹ́yìn òun ni Malaika jẹ́ ẹni tó ṣe àpèjúwe re gege bi "my boy." E yìí túnmo sì wí pé, Paso n je ko máa yẹ oniroyin náà wí pé, Malaika kìí se ọrẹ, omo lọ jẹ́ s'oun.

Ìjà lọ sí de lorin dowe, ko si eni ti ko sai mo wí pé imule kan náà ni won.

Ní àkókò tí Paso àti Òṣùpá jọ ń bù ata sì ara àwọn lójú. Eyin Paso ni Malaika wá. Arabambi ni gbogbo won, eyin K1 ni gbogbo wọn to si. Ṣùgbọ́n lónìí, erin ni Malaika àti K1 ń rìn sì Osupa.

Kí ló wà fà wàhálà láàrín Paso àti Mailaka?

Àlàyé ń tèsíwájú

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment