To ba je wi pe ẹnikẹ́ni lọ lè ṣe oniduro fún Seun Egbegbe ni, bóyá kò bá ti bo ninu laasigbo to kosi.
Láti gba beeli Seun Egbegbe, ile ejo ni yóò san milionu márùn-ún náírà, enikeji re, Oyekan Ayọ̀mide, tí won jo mú naa yóò san iye owó kan náà.
Leyin èyí, enikookan wọn yóò wá óniduro mejimeji.
Okan ninu awon oniduro naa gbogbo je oga onileburu merindinlogun(level 16) lenu ise ijoba.
Ẹni náà gbogbo ni dukia ilẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Eko, ó sì gbodo setan lati ko àwọn ìwé ilẹ̀ náà sile.
Yato si èyí, ẹnì náà yóò tún fi kaadi irinna (International passport) re silẹ. Lara ohun ti oniduro yóò tún ṣe ni ìbúra níwájú adajo.Ile ejo yóò tún gbà adiresi ilé àti ibi ise oniduro naa.
Pabambari ibè wá ní wí pé, àwọn oniduro kọ̀ọ̀kan yóò tún kó 2.5 million kalẹ gẹ́gẹ́ bí ohùn ìdúró.
Ohun tó sì dájú ni wi pe, ti Seun Egbegbe bá salo, gbogbo nnkan wọnyi ni wọn yóò padanu.
Ní èyí tí ọdún tuntun ń sún mọ́lẹ̀ yìí, àwọn kan tun be Segun Egbegbe wo, eleyii ti won jábọ̀ ohun to sọ
E yẹ àtẹ yìí wo fún abala kẹta iroyin yii.
0 comments:
Post a Comment