Smiley face

Àwọn ẹṣọ aṣọ́bodè (Customs) se bẹbẹ nílùú Eko: Ẹ wá wo ẹ̀jẹ̀ ènìyàn lójú titi

Ni ìdajì àná, 17-02-2018, ní àwọn ẹ sọ aṣọ́bodè (Custom) ṣekú pa enikan ni agbegbe Abúlé Ẹ̀gbá tó wà ní ìlú Èkó nígbà tí àwọn méjì mii fara pá. Ijamba yìí ló wáyé nígbà tí àwọn ẹsọ aṣọ́bodè náà sina ibon bole nígbà tí wọn lé àwọn onifayawo kan bọ láti Sango Ota ni nnkan bí ago mefa ìdajì

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment