"Èdùmàrè mo dúpẹ́, nítorí ó bu kún mi kọjá òye mi. Mo ti bá ọba jẹun, mo sì ti bá ìjòyè jókòó tayo alọpọn. Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Edua Òkè tó fún mi lẹbi rere, ọrẹ àti àwọn olólùfẹ́ mi gbogbo." - Muyiwa Ademola #HappyBirthday
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment