Àwọn Yoruba bọ, wọn ti ìró bá lo fogún ọdún, ọjọ́ kan ṣoṣo ni òótọ́ yóò lè bá.
Stephanie Otobo to parọ nígbà kan wí pé, àlè òun ni Apostle Suleman jẹ ati wí pé àìmọye ìgbà ni òun fi seyun fún ọkùnrin náà tí padà jewọ wí pé irọ́ ni gbogbo oro naa.
Stephanie Otobo tí bẹ Apostle Sulaiman wí pé kò dariji òun àti wí pé, àwọn olóṣèlú kan ni wọn ti oun láti bá ojisẹ Ọlọ́run náà ni orúkọ jẹ.
0 comments:
Post a Comment