Bí o tilẹ̀ jẹ́ wí pé ìwádìí fi hàn wí pé, àwọn olórí láàfin Ọba Lamidi Adeyemi III tí ń lọ bí mọ kànlá (11). Ṣùgbọ́n ipò Olori Nihinlola Abibat tí wọn tún pe ni Ìyá Adodo (79yrs) kò yẹ láàfin gege bí olorì àgbà pátápátá.
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe sọ fún wa, Aláàfin Adeyemi II Adeniran tó jẹ́ bàbà alaafin asiko yii ni olorì tó lè ní ìgbà (200) nígbà tó wà lóde Oyo.
Kosi ohun tí a lè fi àyè ọba, ṣe bí ẹ ri ọmọ Atanda bo se n jaye. Layiwola ọmọ Adeniran, ọkọ dúdú, ọkọ pupa, ọkọ bọrọkinni, irumolẹ ọkọ Abibatu.
0 comments:
Post a Comment