Smiley face

Ọmọge to di síwájú di sẹ́yìn laye ń ko jẹ báyìí

Àwọn ènìyàn tí wọn kowo ra bebi onike fún ibalopo lọkọlaya ni wọn jẹri wí pé, gbogbo ona ni bebi yìí fi dára jù kí ènìyàn fẹ ìyàwó obirin ènìyàn gidi sílè lọ.

Bebi yìí kii beere owó, kò lè yanle, tí àwọn bá pẹ wọlé kò ní bínú. Bákan náà ni igbakuugba ni àwọn lè ki i mọ́lẹ̀ láti bá ní ajosepo láìsí konpileeni.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment