Onarebu Hosea Ibi ọkàn nínú àwọn ọmọ ilẹ̀ igbimo asofin ipinle Taraba tí wọn jigbe ni Dec 30, 2017 ni wọn ti padà rí òkú rẹ lórí akitan báyìí. Àwọn agbofinro sì ń sise ìwádìí lowo lati mo àwọn amokunseka tí wọn sise ibi náà.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment