Leyin ìkọlù àwọn ọmọ ikọ Boko Haram ni Government Girls Technical College, Dapchi, nipinle Yobe, àwọn ọmọ iléèwé méjìdinlaadota lọ tí sọnù báyìí tí wọn sì n wá won.
Ìṣẹ̀lẹ̀ to wáyé lọjọ ajé yìí tí ń fà rukerudo, eléyìí tí opolopo àwọn òbí àti olùkọ́ tí ń kó ọkàn sókè lai lè sọ pàtó ibi tí àwọn ọmọ náà wá báyìí.
Ṣùgbọ́n sá, ìjọba àpapọ̀ tí tá àwọn ọmọ ológun nìdí kan, láti wá àwọn ọmọ náà lawari
0 comments:
Post a Comment