Smiley face

Akópa mẹfa tí wọn jà nínú idije #BBNaija tí padà láti South Africa

Àwọn akópa mẹfa àkọ́kọ́ tí wọn jà nínú idije Big Brother Naija tí ń lọ lọ́wọ́ ni orileede South Africa tí wọlu Naija wá. Àwọn akópa náà ni Kbrule, Princess, Khloe, Dee One, Bitto ati Vandora.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment