Àìmọye ìgbà ni Hakeem Effect tí gba àmì ẹyẹ gẹ́gẹ́ bí asaraloge to pegede julọ. Ayafi ti ènìyàn bá ń pegan lásán, ìṣe owó Hakeem a máa jomiloju gidi gan, bákan náà la sì má báni leru. Ise owo Hakeem Effect to fakiki yìí ló mú wá gba wí pé, kii se ènìyàn lásán, akanda ènìyàn ni i ṣe
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment