Ipade àwọn ìgbìmò ilu, council of state, wayé lónìí ní ìlú Abuja.
Fún oye kíkún, njẹ àwọn wo gan-an ni wọn lẹtọ láti kópa ninu ìpàdé ìgbìmò ìlú?"
1. Ààrẹ, ẹni tó jẹ́ alága ìpàdé
2. Igbakeji Ààrẹ, ẹni tó jẹ́ igbakeji alága ìpàdé.
3. Gbogbo Aare àti adari ijoba àpapọ̀ àtijọ́
4 Gbogbo Adájọ́ àgbà ilẹ̀ Nigeria àtijọ́
5 Ààrẹ ilẹ̀ igbimo asofin àgbà
6 Adari ilé igbimo asoju-sofin
7. Àwọn gómìnà pátá àti
8. Adájọ́ àgbà ilẹ Nàìjíríà
Èyí tó wáyé lónìí ni i ṣe ẹlẹẹkẹta irú ẹ ti yóò wayé láti ìgbà tí Aare Buhari tí gorí aleefa.
Bákan náà la tún gbọ wí pé Omowe Goodluck Janathan kò wá sí ìpàdé tó ní.
0 comments:
Post a Comment