Smiley face

Ohun tí ẹ kò mọ nípa Shina Rambo ògbólógbòó ọlọ́ṣà (2)

Shina Rambo, ògbólógbòó ọlọ́ṣà to fi ìgbà kan fitinati goosu ìwọ oòrùn Nàìjíríà àti orileede Benin rí ní o ti na owó tótó àádọ́ta milionu (50m) lọjọ kan ṣoṣo.

Bákan náà, Shina Rambo ati awon ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ tí wá ọkọ bí ogójì (40) lẹẹkan náà láti ipinle Eko lọ sí orile-ede Benin tí ẹnikẹ́ni kò sì dá dúró tàbí yẹ lọ́wọ́ wo nítorí wí pé ó jẹ́ alágbára ènìyàn.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment