#Photo2
Ọkan ninu awọn ọmọge ayélujára tí orúkọ rẹ ń jẹ Romans Goddess lọ tí fesi padà sí ìbéèrè oniroyin ayélujára kan tó béèrè wí pé, ṣe ọmọbìnrin náà dogbon sì ọmu gelete tó gbé sì igaaya ni àbí bẹẹ lo gbé wa latọrun.
Èsí ọmọge náà ni yìí :
You think I have time to spend money on "surgery,”
“My boobs are very real. I don’t need to convince you or anybody but I can tell you they are real. I was born this way and I will remain this way” - Romans Goddess
Fún ipolowo àti ikede
+2348032394964
yemoford@gmail.com
0 comments:
Post a Comment