Ìròyìn Justine ọmọ ọdún mokanla tí bẹ̀rẹ̀ si ni tan káàkiri àgbáyé báyìí pẹ̀lú bí igbe ayé rẹ ṣe ni ìtumò leyin ìṣe abẹ oṣù márùn-ún. Gẹ́gẹ́ bí alaye tí a gbọ, odindi oṣù márùn-ún ni Justine fi wá lábẹ́ ìtọ́jú eléyìí to là ìṣe abẹ lọ.
Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ohun gbogbo, ayọ̀ àti ìdùnnú padà di ti Justine
0 comments:
Post a Comment