Smiley face

Gómìnà Ajimobi tún dá àríyá ìgbéyàwó eleekeji sílè fún ọmọ rẹ

Leyin  ìgbéyàwó to wáyé ní ìlú Kano láàárín Abolaji Ajimobi, ọmọkùnrin gómìnà Ìpínlẹ̀ Oyo ati aya rẹ, Fateema Ganduje to jẹ ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Kano, gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tún dá ayẹyẹ ìgbéyàwó eleekeji sílè ni ìlú Ìbàdàn lánàá , 10/11/2018 

Bákan náà la tún yọ gbọ wí pé, ayẹyẹ ìgbéyàwó ẹlẹẹkẹta yóò tún wáyé nílùú Dubai. Ó dàbí wí pé fíìmù tó gùn gan-an ni ìgbéyàwó àwọn ọmọ gómìnà méjì yìí.



E lé wo àwọn foto to ku NIBI 

https://www.facebook.com/groups/letakanako/permalink/1885438751507425/

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment