Gbogbo Ìbàdàn tí ń rọ kẹ̀tíkẹ̀ti báyìí láti gbalejo Omoyele Sowore, olootu àgbà àti oludasile ilé ìṣe ìròyìn Sahara Reporters, ẹni tí ń múra láti díje fún ipò aare ilé Nàìjíríà.
Ogbeni Sowore ńbọ n'Ibadan fún ìpàdé ìjíròrò níbi tí ó ti má ṣe àlàyé èrò àti àwọn ìpinnu rẹ nípa ipò aare tó fẹ́ díje fún.
Edmund Obilo, akíkanjú oniroyin ọlọtẹlẹmuyẹ ni má ṣe atokun ètò náà.
Date: April 6th 2018
Time: 11 am prompt.
Venue: Onosode Hall, International Conference Center, 2nd Gate, University of Ibadan.
0 comments:
Post a Comment