Orísìírísìí aṣọ oge tuntun ni àwọn onise oge tí ń ṣe àfihàn re lagbaye báyìí. Eléyìí tí pupọ rẹ tàbùkù àṣà àti ìṣe àwọn ènìyàn dúdú. Ṣùgbọ́n nínú ilakaka àwọn ènìyàn dúdú, àwọn aṣọ atowunrinwa tí ń sá siwa labe aṣọ.
Kini ohun tí ẹ lè sọ nípa aṣọ oge tuntun
0 comments:
Post a Comment