Ọkan ninu awọn Senator Abuja tí ń soju ipínlẹ̀ Kaduna, Ọ̀gbẹ́ni Shehu Sani, lo ti tàn imole sì ohun tó rújú báyìí nípa iye owó amurele àwọn ọmọ ilẹ̀ igbimo asofin àgbà Abuja.
Nínú ọ̀rọ̀ Senator to jẹ ọmọ ẹgbẹ́ APC yìí ló ti sọ wí pé, yàtò si N700,000 to jẹ owó oṣù àwọn, N13.5 million ni owo ajemonu àwọn.
Àṣírí tí Shehu Sani tú sí owó àwọn oniroyin yìí tí bí àwọn ọmọ ilẹ̀ igbimo asofin nínú. Wọn sì ti ṣe ìlérí láti fi ìjìyà tó tọ́ je Senator Shehu Sani
0 comments:
Post a Comment