Smiley face

Igbo Sambisa: Ohun tí àwọn sójà ń ṣe lojo àjíǹde ni yìí

Láàárín àwọn ọ̀tá, níbi tí ota ìbọn tí ń fò bí ẹyẹ ojú ọ̀run, nínú igbó aginjù Sambisa, àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà péjọ pọ̀ fún ìsìn àjíǹde.

Wọn ba ara sọ ọrọ Ọlọhun. Wọn sọ nípa ikú àti àjíǹde Jésù Olùgbàlà. Wọn so nípa ìdí tí orúkọ àwọn akọni kìí se parẹ́ nínú ìtàn. Wọn ní àwọn akọni má gbé ìgbé ayé wọn fún àwọn ènìyàn, wọn si má ń  setan láti fi èmi wọn silẹ fún ìran ènìyàn.

Isẹ ńlá ni àwọn sójà wá ń ṣe, kí Edumare má fi ààbò rẹ bò wọn.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment