Ẹlẹ́dẹ̀ abàmì tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wí pé, Donald J. Trump ìlú Amẹrika ni yóò jaye olubori gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí kéde wí pé ikọ́ a...
Read More
Home / Ere Idaraya
Showing posts with label Ere Idaraya. Show all posts
Showing posts with label Ere Idaraya. Show all posts
Russia 2018: Pele àti Maradona tí wọlé
Ààrẹ ìlú Russia 🇷🇺, Putin, fún ra rẹ lo kí Pele kaabọ si orile-ede Russia fún igbaradi ìfẹ́ agbaye tí yóò wayé ni orile-ede náà. Pele ọmọ...
Read More
"Mikel Obi kìí rán àwọn ènìyàn rẹ lọ́wọ́"- Ẹbi Mikel kan tí sọ̀rọ̀
Ọmọkùnrin kan lórí ayélujára ti gbìyànjú láti fi aṣọ Mikel Obi yidọti. Ọmọkùnrin náà ṣe àlàyé ara rẹ gẹ́gẹ́ bí ọmọ àbúrò bàbà Mikel. Ó ni ar...
Read More
Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ
Ẹ kíyèsí, àlàyé to bá ti ní nọ́mbà kìí rújú. Nǹkan bí ọdún méjìlélógún lo fi tukọ̀ ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal gẹ́gẹ́ bí akonimọọgba. Igba mẹta ...
Read More
Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí
Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO....
Read More
Anthony Joshua Oluwafemi to bẹru
Anthony Olaseni Oluwafemi Joshua ṣe àfihàn àwọn àmì ẹyẹ rẹ lẹ́yìn to fo gbogbo ẹnu Joseph Parker nínú ìjà to wáyé lọjọ Satide, 31/03 /2018 ...
Read More
Jatijati ni Anthony Joshua na Joseph Parker ni àlè ana
Ninu idije ese kíkan tó wáyé ní ilẹ Biritiko lọjọ Satide to kẹyin oṣù kẹta, 31/03/2018, àná fò lójú ni Anthony Joshua na Joseph Parker
Read More
A má tí orí Morocco bonu omi gbígbóná ni to bá di Sunday - Super Eagles
Asekagba idije Chan 2018 eléyìí to ń wáyé ní orileede Morocco ni yóò wá sopin lọjọ Sande tí ń bo yii. Asekagba náà yóò sì wáyé láàárín Sup...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)