Bi eniyan ba ni iran tan, nigba naa niran tun ku seyin. E wo tun ni tisa abileko ti n ba akekoo re to je okunrin sun. Lauren Cox, olukob...
Read More
Home / Iroyin Agbaye
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts
Omobirin ti n ba baba re sun lai mọ ti pa ara rẹ leyin ti asiri tu
Omobirin ẹni ọdun metalelogun kan, Sthabile Mkhwanazi, lo ti seku pa ara re leyin ti oye ye wi pe baba to bi i lọmo lo yan gege bi Suga...
Read More
Iwadii tuntun nipa baalu ile Egypt to ja lulẹ
Iwadii tuntun to jade fidi rẹ mulẹ wi pe baalu ilẹ Egypt to ja seefin ni awon akoko kan loju orun ko to di wi pe o jalule. Sugbon ohun t...
Read More
"66 eniyan lo wa ninu baalu Egypt to poora" Awon alase lo so bee
Awon alase oko ofurufu ile Egypt kede wi pe, awon eniyan merindinlaadorin (66) lo wa ninu baalu MS804 eleyii to sadeede poora nigba to n ...
Read More
Oludasile FACEBOOK se ojo ibi odun mejilelogbon (32)
Oludasile ati alase FACEBOOK agbaye, Mark Zuckerberg , se ojo ibi odun mejilelogbon (32) laaarin ore ati ebi re. Igba odun, odun kan n...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)