Awon alase oko ofurufu ile Egypt kede wi pe, awon eniyan merindinlaadorin (66) lo wa ninu baalu MS804 eleyii to sadeede poora nigba to n bo lati ilu France ni Ojobo to koja yii.
Awon alase ilu Egypt ni oseese ko je awon agbesunmomi alakatakiti esin ni won ta baalu naa lofa lati oju orun. Sugbon awon alase ilu France ni o ti yaju lati le salaye ni pato nipa ohun to ja baalu naa lule.
Sugbon sa, awon onise iwadii ti bo soju ise lati mo ibi ti baalu naa wole si.
Olayeni Oniroyin Agbaye naa le n ka yii. Ijamba buruku ko ni sele loode wa o.
E ku ikale!

0 comments:
Post a Comment