Awon eniyan ti won fura si gege bi alakatakiti agbesunmomi gbiyanju lati kolu ile igbimo ile Biritiko lana, 22:03:07.
Read More
Home / Iroyin Agbaye
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts
Awon oyinba pon Oonirinsa le niluu London: Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi gbayi niluu Oba
Ka ma paro, awon oyinbo se aponle Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi niluu London. Won se alaye Arole Oodua gege bi ologbon eda ati asaaju to s...
Read More
Orekelewa obabirin MOREMI gbe asa Yoruba soke niluu London
Sebi e mo wi pe Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi si wa niluu London, lara awon to koworin pelu Ojaja II ni Obabirin Moremi asiko yii eley...
Read More
Omo odun merin yii lo ko lati fi iya re to salaisi sile
Orisa bi iya ko si laye, Edumare ma je awon omo wa di omoolomo. Omo odun merin yii ni aworan re ti bere si ni fo kiri ayelujara pelu bo ...
Read More
Alakatakiti esin Islam (ISIS) se meje (7) ninu awon omo ogun won ninu omi gbigbona: Ki ni idi abajo?
Sebi Yoruba ni adiẹ kii jefun ara won ni? Oro ko ri bẹẹ pelu awon omo alakatakiti esin Islam, ISIS. Onidajo Sharia Awon omo ogun...
Read More
[foto] Nicki Minaj pate kaka nla
Ogbontarigi akorinbirin ilu Amerika, Nicki Minaj , ẹni odun metalelọgbọn (33), ti se afihan awon foto re tuntun eleyii ti gbogbo ibara i...
Read More
Awon omo ileewe sagbako iku ojiji leyin ti won jo makosa tan
Awon omo ileewe giga kan niluu Kenya ni won ti sagbako iku ojiji lana, 1/7/06, nigba ti won ti ode ariya alaso funfun bo. Awon mejo ni ...
Read More
Awon foto Ooni Enitan Ogunwusi niluu Amerika
Die ni yii lara awon foto ayeye Ooni Ogunwusi niluu Amerika.
Read More
Awon aworan tuntun Amber Rose
Onkorinbirin ilu Amerika, Amber Rose, gbe ara oge re yo niluu New Jersey.
Read More
Samuel Eto'o so yigi alarinrin pelu iya awon omo re niluu Italy
Agbaboolu omo ile Cameroon, Samuel Eto'o, ti pada so yigi pelu ololufe re to tun je iya awon omo re meji, Georgette Tra, ninu It...
Read More
Ayeye ikeyin Muhammad Ali waye ni Kentucky niluu Amerika
Aimoye ero lo peju si Louisville, Kentucky niluu Amerika lojo kesan an osu kefa odun yii lati se ayeye ikeyin ati adura fun Muhammad A...
Read More
Jay Z gbalejo Don Jazzy ati Tiwa Savage niluu Amerika
Don Baba ti mu Tiwa Savage lo se abewo si ogbontarigi onkorin ile Amerika, Jay Z. Ohun ti a gbo ni wi pe, adehun kan ni won lo fidi re mu...
Read More
Awon foto ti Muhammad Ali ya keyin ni yii
Foto yii ni Muhammad Ali ya keyin saaju ko to jade laye. Inu osu keta odun yii ni won ya foto naa, eleyii ti Zenon Texeira ya ninu ile Mu...
Read More
Rihanna n jaye leti omi okun
Rihanna, gbajugbaja onkorinbirin ilu Amerika, n jaye ori re leti odo pelu igo bia to fi n sorun ajija re.
Read More
Ayọ ọmọ tuntun: Wèrè bimọ soju titi
Obirin wèrè oloyun kan lo sadeede n rọbi loju pọpọna ki awon abiyamọ aye to sun mọ ọ lati se iranlowo fun un. Obirin lọmọ to bi, orileed...
Read More
Won ti se idajọ iku fun omo Naijiria ni Saudi Arabia
Nibayii, iwe iroyin The Guardian tiluu okeere ti gbe e jade wi pe, awon alase ilu Saudi ti se idajo iku fun omo Naijiria kan eleyii ti ...
Read More
Inaki ti won pa ti da awuyewuye silẹ kaakiri agbaye
Isẹlẹ kan to sẹlẹ ninu ọgba eranko Cincinnati Zoo to wa ni ilu Ohio ni orileede Amerika ti di ohun ti gbogbo agbaye n bu ẹnu atẹ lu bayii...
Read More
Omo ologun subu yakata nibi won ti n yan
Okan ninu awon omo ologun lo sadeede subu nibi ayeye kan to waye ni North Yorkshire eleyii ti enikeni ko le so pato ohun to mu o...
Read More
Won ti bere isin ikeyin fun awon to ku ninu baalu EgyptAir MS804
Awon eniyan ti won padanu eniyan won ninu ijamba oko ofurufu to waye niluu Egypt ti bere isin ikeyin fun awon eniyan won. A tile ri gbo ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)