Jay Z gbalejo Don Jazzy ati Tiwa Savage niluu Amerika Olayemi Oniroyin 6/08/2016 01:50:00 pm Foto , Iroyin Agbaye , Orin Edit Don Baba ti mu Tiwa Savage lo se abewo si ogbontarigi onkorin ile Amerika, Jay Z. Ohun ti a gbo ni wi pe, adehun kan ni won lo fidi re mu eleyii to ni i se pelu orin ajumọkọ kan to fẹ waye laarin ikọ mejeeji. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Awon omo ileewe sagbako iku ojiji l...Saheed Osupa Ọba Orin ti de pelu No...Báyìí ni Tatalọ ṣe jẹyo nínú orúkọ ... Jay Z gbalejo Don Jazzy ati Tiwa Savage niluu Amerika Reviewed by Olayemi Oniroyin on 6/08/2016 01:50:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment