Omo odun merin yii lo ko lati fi iya re to salaisi sile Olayemi Oniroyin 8/01/2016 07:40:00 pm Iroyin , Iroyin Agbaye Edit Orisa bi iya ko si laye, Edumare ma je awon omo wa di omoolomo. Omo odun merin yii ni aworan re ti bere si ni fo kiri ayelujara pelu bo se ko lati fi iya re to salaisi sile. Gbogbo igba ni pariwo pe iya re bi ko dide. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Alakatakiti esin Islam (ISIS) se me...[foto] Nicki Minaj pate kaka nlaAwon omo ileewe sagbako iku ojiji l... Omo odun merin yii lo ko lati fi iya re to salaisi sile Reviewed by Olayemi Oniroyin on 8/01/2016 07:40:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment