Ayọ ọmọ tuntun: Wèrè bimọ soju titi Olayemi Oniroyin 6/03/2016 09:00:00 pm Iroyin Agbaye Edit Obirin wèrè oloyun kan lo sadeede n rọbi loju pọpọna ki awon abiyamọ aye to sun mọ ọ lati se iranlowo fun un. Obirin lọmọ to bi, orileede Zambia ni isẹlẹ naa ti waye. Ọkunrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Victor lo si gbe aworan naa sori Facebook. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Omo odun merin yii lo ko lati fi iy...Alakatakiti esin Islam (ISIS) se me...[foto] Nicki Minaj pate kaka nla Ayọ ọmọ tuntun: Wèrè bimọ soju titi Reviewed by Olayemi Oniroyin on 6/03/2016 09:00:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment