Samuel Eto'o so yigi alarinrin pelu iya awon omo re niluu Italy Ola Daviva 6/14/2016 09:21:00 pm Ere , Iroyin Agbaye Edit Agbaboolu omo ile Cameroon, Samuel Eto'o, ti pada so yigi pelu ololufe re to tun je iya awon omo re meji, Georgette Tra, ninu Italo. Igbeyawo alayo yii lo waye ni Stezzano to wa lorileede Italy. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Samuel Eto'o so yigi alarinrin pelu iya awon omo re niluu Italy Reviewed by Ola Daviva on 6/14/2016 09:21:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment