Ayọ ọmọ tuntun: Wèrè bimọ soju titi Olayemi Oniroyin 6/03/2016 09:00:00 pm Add Comment Edit Obirin wèrè oloyun kan lo sadeede n rọbi loju pọpọna ki awon abiyamọ aye to sun mọ ọ lati se iranlowo fun un. Obirin lọmọ to bi, orileed... Read More
Won ti se idajọ iku fun omo Naijiria ni Saudi Arabia Olayemi Oniroyin 5/30/2016 03:56:00 pm Add Comment Edit Nibayii, iwe iroyin The Guardian tiluu okeere ti gbe e jade wi pe, awon alase ilu Saudi ti se idajo iku fun omo Naijiria kan eleyii ti ... Read More
Inaki ti won pa ti da awuyewuye silẹ kaakiri agbaye Olayemi Oniroyin 5/30/2016 03:37:00 pm Add Comment Edit Isẹlẹ kan to sẹlẹ ninu ọgba eranko Cincinnati Zoo to wa ni ilu Ohio ni orileede Amerika ti di ohun ti gbogbo agbaye n bu ẹnu atẹ lu bayii... Read More
Omo ologun subu yakata nibi won ti n yan Olayemi Oniroyin 5/22/2016 11:04:00 am Add Comment Edit Okan ninu awon omo ologun lo sadeede subu nibi ayeye kan to waye ni North Yorkshire eleyii ti enikeni ko le so pato ohun to mu o... Read More
Won ti bere isin ikeyin fun awon to ku ninu baalu EgyptAir MS804 Olayemi Oniroyin 5/22/2016 10:44:00 am Add Comment Edit Awon eniyan ti won padanu eniyan won ninu ijamba oko ofurufu to waye niluu Egypt ti bere isin ikeyin fun awon eniyan won. A tile ri gbo ... Read More