Smiley face
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts

Àwọn ọ̀daràn ko ọta ìbọn sínú poosi

Eléyìí ni die lára ìwà idaran tí ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ wá. Orisirisi ète ni àwọn ọ̀daràn ń lo báyìí
Read More

Oṣù márùn-ún ni wọn fi tọju Justine pelu ìṣe abẹ

Ìròyìn Justine ọmọ ọdún mokanla tí bẹ̀rẹ̀ si ni tan káàkiri àgbáyé báyìí pẹ̀lú bí igbe ayé rẹ ṣe ni ìtumò leyin ìṣe abẹ oṣù márùn-ún. Gẹ́gẹ́...
Read More

Ọkùnrin kan fe ìṣe ìgbéyàwó obìnrin méjì lọ́jọ́ kan naa

Sebi wọn ẹkọnomi wá kò dára ní? Maamu kan tó jẹ́ ajeseku lo tí setan báyìí láti ṣe ìgbéyàwó fún obìnrin méjì lọ́jọ́ kan naa ni ìpínlè Abia ...
Read More

Délé Momodu sedaro lẹ́yìn Ọ̀jọ̀gbọ́n Akinwunmi Isola to ku

Délé Momodu ṣe ìdárò olùkọ́ rẹ ni iléèwé nígbà kan rí, Ọ̀jọ̀gbọ́n Akinwunmi Isola, to rebi àgbà ń rè
Read More