Iku opin odun fo lo lori Dele Momodu Olayemi Oniroyin 12/28/2015 04:30:00 pm Add Comment Edit Gege bi Ayinla Omowura se so inu awo orin re kan, "ori ti o royin ogun ko ni ku." Eyi gan-an ni a le fi se apejuwe oga oniroyin, ... Read More
Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi Olayemi Oniroyin 12/27/2015 03:08:00 pm Add Comment Edit Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniya... Read More
Owo ti te Jaguda to lu komisanna olopaa meji ni jibiti Olayemi Oniroyin 12/27/2015 10:04:00 am Add Comment Edit Mohammed Isah Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko r... Read More
Ambode lewaju orin keresimesi nile ijoba Ipinle Eko Olayemi Oniroyin 12/26/2015 05:57:00 pm Add Comment Edit Awon Yooba bo, won ni odoodun la a rorogbo; odoodun laarawusa; sebi odun ko ni de ka ma romo obi lori ate. Aimoye ero pitimu ni ... Read More
"Ko saaye fun Toll-Gate bayii" - Egbe Akoroyin tiluu Eko Olayemi Oniroyin 12/19/2015 10:56:00 am Add Comment Edit E gbe akoroyin, Nigeria Union of Journalists eka ti ilu Eko, ti gbe atejade kan jade eleyii to n ro ijoba apapo lati se atunse si awon o... Read More