Àwọn onwoye nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú tí ṣàlàyé wí pé, kò yẹ kó jẹ ohun ijoloju wí pé oga àgbá àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ yìí tún padà pe Bukola Sàràkí lórí ...
Read More
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts

Sàràkí lè dá Buhari lágbo nu
Inúfu-àyàfu ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC wá báyìí pelu ahesọ ọ̀rọ̀ tí ń lọ kiri wí pé, Ààrẹ ilé igbimo asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí kò ní pẹ fi ẹg...
Read More

Wọn tí yọ orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú ẹsun idigunjale tó wáyé l'Ọffa
Àṣírí tí lu jáde báyìí wí pé wọn ti fà orúkọ Bukola Sàràkí kúrò nínú esun ìdaràn idigunjale tó wáyé nílùú Ọffa níbi tí àìmọye èmi ti ṣòfò. ...
Read More

Ilọrin Afonja tí tẹ́wọ́ gba Omoyele Sowore
Walahi sugar ja nílùú Ilọrin fa nígbà tí Omoyele Ṣòwòrẹ́ gbórí wọlé sílùú Afonja pẹ̀lú àwọn ikọ̀ #TakeItBack Ẹ wolẹ kẹ ẹ wẹnu ọkọ́ ...
Read More

Buhari tí de láti UK: Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Orunmila tí ṣẹlẹ̀ sí Buhari
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí padà wálé láti ìlú Biritiko níbi tó ti lọ yọjú sì dókítà tí ń tọju rẹ. Ní alẹ ọjọ́ Jimoh, 11/05/18, ní bàálù aare b...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)