Ẹni ja ìjàngbara kò yàtò ṣeni tí wọn forí rẹ fagbọn. Ẹni wọn forí rẹ fagbọn kìí dúró jẹ ẹ. Ayafi ẹni Olúwa bá ko yọ. Funmilayo RansomeKuti ...
Read More
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts

"Yato si owó oṣù àwa Senator, 13.5M ni ajemọnu wá losoosu"- Senator kan tí jẹwọ
Ọkan ninu awọn Senator Abuja tí ń soju ipínlẹ̀ Kaduna, Ọ̀gbẹ́ni Shehu Sani, lo ti tàn imole sì ohun tó rújú báyìí nípa iye owó amurele àwọn ...
Read More

Kayode Ogundamisi tí ṣe àlàyé àwọn irumole tí ń wọn jẹ dollar lowolowo
"Ìgbà ni gbogbo nǹkan láyé. Ayé ìgbà kan ni Government Ekpemupolo tí inagijẹ rẹ ń jẹ Tompolo, Soboma George, Ateke Tom, Mujahid Dokubo-...
Read More
Ohun tí àwon ènìyàn ṣe láti fojú kan Buhari ni Plateau bani lẹ́rù
In Plateau, kosi ohun tí awon ènìyàn kò ṣe tán láti fojú kan Buhari. Àwọn kan gùn orí igi, àwọn kan gùn ilé alájà, díẹ báyìí lo kù kí àwọn k...
Read More
Ìpínlẹ̀ Plateau gbé Buhari sókè lonii
Ààrẹ Muhammadu Buhari, ẹni tí wọn fún ni inagijẹ "Baba go slow" ní kété to gorí aleefa látàrí aitete yàn àwọn minisita rẹ, lo ti p...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)