Home /
Uncategories /
Angeli To N Pinre
Angeli To N Pinre
Bí àlá ló jẹ lójú wa.
Ohun ojú rí kọjá ohun ti igbabọ wa le gbé.
Ìyànú lo jẹ fun wa lati ri erupẹ gbẹrẹfu laaarin òkun.
Yìnyín laaarin ina nla.
Iyanu lo jẹ fun wa.
Nitori àwa ba angeli to pínre pàdá.
Angẹli to n pinre laaarin ọwọn ati iṣẹ
Angeli To N Pinre
Reviewed by
Olayemi Oniroyin
on
8/25/2012 04:48:00 pm
Rating:
5
0 comments:
Post a Comment