Smiley face

IPINNU MI DA?

Kilode ti o je wi pe ohun taa mo a ki i se, ohun ti ko ye wa laa rawo le?

Nnka bi odun mewa seyin, mo pade okunrin kan ti oun ati awon kan jo un soro nibi kan.

Okunrin yii so nipa ibi kan wi pe eniyan ko gbodo de ibe gbadura si Olorun fun ojo meje ki adura eniyan ma gba kiakia.

O n so pelu idaniloju ni, nitori eyi han ninu isoro si re.

Mo wo okunrin yii titi, safeti orun re ti fele de ibi wi pe awon owu ti won fi hun aso naa ti n dogbon takete si ara won.

Ti aso dudu ba ti n sa, iru aso bee a fe maa di funfun. Ohun to ba le mu eniyan sakiyesi wi pe aso funfun ti n gbo, se e mo wi pe oro koja bikiefu nu-un.

Ninu okan mi, mo n ro wi pe kilode ti okunrin yii ko lo sibi to n wi ki igbe aye le yi pada?


Opolopo ohun taa mo, a ki i se. Ohun ti ko ye wa ni i joba lokan aya wa.


Bakan naa ni omidan ti mo pada ti n je Iretiola. Iretiola je eniyan to lomi lara daada, aridaju si wa wi pe yoo si sanra siwaju si pelu irisi ara re. Sugbon ko wu Ireti lati sanra si i rara nitori gbogbo igba lo maa n se afihan eleyii to ba n soro.

Sibesibe, sokoleeti ni o mo ponla ni gbogbo igba. Oye si ye debi to mo ise ti iru ounje bayii n se lara.


Kilode to nira fun wa lati se opolopo ohun taa mo to le ran wa lowo?

Aimoye ipinnu la se ni ibeere odun nipa ba o se tesiwaju. Melo ninu awon nnkan wonyii lati gbe se?

Osu to keyin abala akoko ninu ilata odun la tun bere yii o, emi kan ni n ran o leti ni.

Se gbogbo ohun too lo se ni ibere odun lo ti n se?

Olayemi, mo pada si k?bi iroyin.
28EEEAE2
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment